1 Sámúẹ́lì 14:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Àwọn ọmọkùnrin Sọ́ọ̀lù ni Jónátánì, Íṣífì àti Maliki-ṣúà.+ Ó ní ọmọbìnrin méjì; èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Mérábù,+ àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Míkálì.+ 2 Sámúẹ́lì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ nígbà tí Àpótí Jèhófà wọ Ìlú Dáfídì, Míkálì,+ ọmọbìnrin Sọ́ọ̀lù, bojú wolẹ̀ láti ojú fèrèsé,* ó rí Ọba Dáfídì tó ń fò sókè, tó ń jó yí ká níwájú Jèhófà; ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pẹ̀gàn rẹ̀ nínú ọkàn rẹ̀.+
49 Àwọn ọmọkùnrin Sọ́ọ̀lù ni Jónátánì, Íṣífì àti Maliki-ṣúà.+ Ó ní ọmọbìnrin méjì; èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Mérábù,+ àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Míkálì.+
16 Àmọ́ nígbà tí Àpótí Jèhófà wọ Ìlú Dáfídì, Míkálì,+ ọmọbìnrin Sọ́ọ̀lù, bojú wolẹ̀ láti ojú fèrèsé,* ó rí Ọba Dáfídì tó ń fò sókè, tó ń jó yí ká níwájú Jèhófà; ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pẹ̀gàn rẹ̀ nínú ọkàn rẹ̀.+