14 Wò ó, mo ti sapá gan-an láti pèsè ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) tálẹ́ńtì wúrà sílẹ̀ fún ilé Jèhófà àti mílíọ̀nù kan (1,000,000) tálẹ́ńtì fàdákà pẹ̀lú bàbà àti irin+ tó pọ̀ gan-an débi pé kò ṣeé wọ̀n, mo sì ti pèsè àwọn ẹ̀là gẹdú àti òkúta+ sílẹ̀, àmọ́ wàá fi kún wọn.