Jẹ́nẹ́sísì 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+ Diutarónómì 33:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Aláyọ̀ ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Ta ló dà bí rẹ,+Àwọn èèyàn tó ń gbádùn ìgbàlà Jèhófà,+Apata tó ń dáàbò bò ọ́,+Àti idà ọlá ńlá rẹ? Àwọn ọ̀tá rẹ máa ba búrúbúrú níwájú rẹ,+Wàá sì rìn lórí ẹ̀yìn* wọn.” Sáàmù 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́, ìwọ Jèhófà ni apata tó yí mi ká,+Ògo mi+ àti Ẹni tó ń gbé orí mi sókè.+
15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+
29 Aláyọ̀ ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Ta ló dà bí rẹ,+Àwọn èèyàn tó ń gbádùn ìgbàlà Jèhófà,+Apata tó ń dáàbò bò ọ́,+Àti idà ọlá ńlá rẹ? Àwọn ọ̀tá rẹ máa ba búrúbúrú níwájú rẹ,+Wàá sì rìn lórí ẹ̀yìn* wọn.”