-
2 Àwọn Ọba 3:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jèhórámù+ ọmọ Áhábù di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà ní ọdún kejìdínlógún Jèhóṣáfátì ọba Júdà, ọdún méjìlá (12) ló sì fi ṣàkóso.
-
-
2 Àwọn Ọba 3:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Síbẹ̀, àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí Jèróbóámù ọmọ Nébátì mú kí Ísírẹ́lì dá ni òun náà ń dá.+ Kò jáwọ́ nínú wọn.
-