2 Kíróníkà 19:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jéhù+ ọmọ Hánáánì+ aríran jáde lọ bá Ọba Jèhóṣáfátì, ó sì sọ fún un pé: “Ṣé èèyàn burúkú ló yẹ kí o máa ràn lọ́wọ́,+ ṣé àwọn tó kórìíra Jèhófà ló sì yẹ kí o nífẹ̀ẹ́?+ Nítorí èyí, ìbínú Jèhófà ru sí ọ. 2 Kíróníkà 20:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ní ti ìyókù ìtàn Jèhóṣáfátì, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ Jéhù+ ọmọ Hánáánì,+ èyí tó wà nínú Ìwé Àwọn Ọba Ísírẹ́lì.
2 Jéhù+ ọmọ Hánáánì+ aríran jáde lọ bá Ọba Jèhóṣáfátì, ó sì sọ fún un pé: “Ṣé èèyàn burúkú ló yẹ kí o máa ràn lọ́wọ́,+ ṣé àwọn tó kórìíra Jèhófà ló sì yẹ kí o nífẹ̀ẹ́?+ Nítorí èyí, ìbínú Jèhófà ru sí ọ.
34 Ní ti ìyókù ìtàn Jèhóṣáfátì, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ Jéhù+ ọmọ Hánáánì,+ èyí tó wà nínú Ìwé Àwọn Ọba Ísírẹ́lì.