1 Àwọn Ọba 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà gbẹnu Jéhù+ ọmọ Hánáánì+ kéde ìdájọ́ sórí Bááṣà pé: 2 Kíróníkà 19:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jéhù+ ọmọ Hánáánì+ aríran jáde lọ bá Ọba Jèhóṣáfátì, ó sì sọ fún un pé: “Ṣé èèyàn burúkú ló yẹ kí o máa ràn lọ́wọ́,+ ṣé àwọn tó kórìíra Jèhófà ló sì yẹ kí o nífẹ̀ẹ́?+ Nítorí èyí, ìbínú Jèhófà ru sí ọ.
2 Jéhù+ ọmọ Hánáánì+ aríran jáde lọ bá Ọba Jèhóṣáfátì, ó sì sọ fún un pé: “Ṣé èèyàn burúkú ló yẹ kí o máa ràn lọ́wọ́,+ ṣé àwọn tó kórìíra Jèhófà ló sì yẹ kí o nífẹ̀ẹ́?+ Nítorí èyí, ìbínú Jèhófà ru sí ọ.