2 Kíróníkà 27:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní ti ìyókù ìtàn Jótámù, gbogbo àwọn ogun tó jà àti àwọn ọ̀nà rẹ̀, ó wà lákọsílẹ̀ nínú Ìwé Àwọn Ọba Ísírẹ́lì àti ti Júdà.+ Mátíù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ùsáyà bí Jótámù;+Jótámù bí Áhásì;+Áhásì bí Hẹsikáyà;+
7 Ní ti ìyókù ìtàn Jótámù, gbogbo àwọn ogun tó jà àti àwọn ọ̀nà rẹ̀, ó wà lákọsílẹ̀ nínú Ìwé Àwọn Ọba Ísírẹ́lì àti ti Júdà.+