2 Àwọn Ọba 15:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ní ọdún kejì Pékà ọmọ Remaláyà ọba Ísírẹ́lì, Jótámù+ ọmọ Ùsáyà+ ọba Júdà jọba.