1 Àwọn Ọba 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọdún mẹ́tàlá (13) ló gba Sólómọ́nì láti kọ́ ilé* rẹ̀,+ títí ó fi parí ilé náà látòkèdélẹ̀.+