1 Sámúẹ́lì 16:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, Sámúẹ́lì mú ìwo tí òróró wà nínú rẹ̀,+ ó sì fòróró yàn án lójú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀. Ẹ̀mí Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún Dáfídì lágbára láti ọjọ́ náà lọ.+ Lẹ́yìn náà, Sámúẹ́lì dìde, ó sì gba Rámà lọ.+ 1 Sámúẹ́lì 17:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dáfídì jẹ́ ọmọ Jésè ará Éfúrátà+ láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ti Júdà. Jésè+ ní ọmọkùnrin mẹ́jọ,+ ó sì ti darúgbó gan-an ní ayé ìgbà Sọ́ọ̀lù. Mátíù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jésè bí Dáfídì+ ọba. Ìyàwó Ùráyà bí Sólómọ́nì+ fún Dáfídì;
13 Torí náà, Sámúẹ́lì mú ìwo tí òróró wà nínú rẹ̀,+ ó sì fòróró yàn án lójú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀. Ẹ̀mí Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún Dáfídì lágbára láti ọjọ́ náà lọ.+ Lẹ́yìn náà, Sámúẹ́lì dìde, ó sì gba Rámà lọ.+
12 Dáfídì jẹ́ ọmọ Jésè ará Éfúrátà+ láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ti Júdà. Jésè+ ní ọmọkùnrin mẹ́jọ,+ ó sì ti darúgbó gan-an ní ayé ìgbà Sọ́ọ̀lù.