-
Léfítíkù 4:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ohun tó ṣe sí akọ màlúù kejì tó jẹ́ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni kó ṣe sí akọ màlúù náà. Bó ṣe máa ṣe é nìyẹn, kí àlùfáà ṣe ètùtù fún wọn,+ wọ́n á sì rí ìdáríjì.
-
-
2 Kíróníkà 29:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àwọn àlùfáà pa wọ́n, wọ́n sì fi ẹ̀jẹ̀ wọn rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ lórí pẹpẹ, láti ṣe ètùtù fún gbogbo Ísírẹ́lì, nítorí ọba ti sọ pé gbogbo Ísírẹ́lì ni kí ẹbọ sísun náà àti ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà wà fún.
-