-
1 Àwọn Ọba 6:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àwọn òkúta tí wọ́n ti gbẹ́ sílẹ̀+ ni wọ́n fi kọ́ ilé náà, tí a kò fi gbọ́ ìró òòlù, àáké tàbí ohun èlò irin kankan nínú ilé náà nígbà tí wọ́n ń kọ́ ọ lọ́wọ́.
-