-
1 Kíróníkà 11:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àwọn tó jẹ́ olórí àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú nìyí, àwọn àti gbogbo Ísírẹ́lì ló tì í lẹ́yìn nínú ìjọba rẹ̀, kí wọ́n lè fi í jọba gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nípa Ísírẹ́lì.+
-