1 Àwọn Ọba 6:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ó fi òkúta gbígbẹ́ kọ́ ipele mẹ́ta ògiri àgbàlá inú,+ lẹ́yìn náà wọ́n gbé ipele kan ìtì igi kédárì+ lé e. 1 Àwọn Ọba 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọ̀wọ́ mẹ́ta òkúta gbígbẹ́ àti ọ̀wọ́ kan ìtì igi kédárì yí àgbàlá ńlá náà ká bíi ti àgbàlá inú+ ilé Jèhófà àti ibi àbáwọlé* ilé náà.+
36 Ó fi òkúta gbígbẹ́ kọ́ ipele mẹ́ta ògiri àgbàlá inú,+ lẹ́yìn náà wọ́n gbé ipele kan ìtì igi kédárì+ lé e.
12 Ọ̀wọ́ mẹ́ta òkúta gbígbẹ́ àti ọ̀wọ́ kan ìtì igi kédárì yí àgbàlá ńlá náà ká bíi ti àgbàlá inú+ ilé Jèhófà àti ibi àbáwọlé* ilé náà.+