33 Bẹ́ẹ̀ náà ni ó ṣe fi igi ahóyaya ṣe férémù ilẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì,* igun rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin sì dọ́gba.*34 Ó fi igi júnípà ṣe ilẹ̀kùn méjì. Ilẹ̀kùn àkọ́kọ́ ní awẹ́ méjì tó ṣeé pa dé, ilẹ̀kùn kejì sì ní awẹ́ méjì tó ṣeé pa dé.+
7 Bákan náà, wọ́n ti àwọn ilẹ̀kùn ibi àbáwọlé,*+ wọ́n sì pa àwọn fìtílà.+ Wọn kò sun tùràrí mọ́,+ wọn kò sì rú ẹbọ sísun+ ní ibi mímọ́ sí Ọlọ́run Ísírẹ́lì.