4 Ẹ́sírà adàwékọ dúró lórí pèpéle onígi tí wọ́n ṣe fún àpéjọ náà; àwọn tó dúró sápá ọ̀tún rẹ̀ ni Matitáyà, Ṣímà, Ánáyà, Ùráyà, Hilikáyà àti Maaseáyà; àwọn tó sì wà lápá òsì rẹ̀ ni Pedáyà, Míṣáẹ́lì, Málíkíjà,+ Háṣúmù, Haṣi-bádánà, Sekaráyà àti Méṣúlámù.