Nehemáyà 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà. Nehemáyà 12:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Wọ́n dé Ẹnubodè Ojúsun,+ wọ́n sì lọ tààrà sórí Àtẹ̀gùn+ Ìlú Dáfídì+ níbi ìgòkè ògiri lórí Ilé Dáfídì títí lọ dé Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn.
26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.
37 Wọ́n dé Ẹnubodè Ojúsun,+ wọ́n sì lọ tààrà sórí Àtẹ̀gùn+ Ìlú Dáfídì+ níbi ìgòkè ògiri lórí Ilé Dáfídì títí lọ dé Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn.