Àwọn Onídàájọ́ 4:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ lẹ́yìn tí Éhúdù kú, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà.+ 2 Torí náà, Jèhófà fi wọ́n lé ọwọ́ Jábínì ọba Kénáánì,+ tó jọba ní Hásórì. Sísérà ni olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ó sì ń gbé ní Háróṣétì+ ti àwọn orílẹ̀-èdè.* Àwọn Onídàájọ́ 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà,+ torí náà Jèhófà fi wọ́n lé Mídíánì lọ́wọ́ fún ọdún méje.+
4 Àmọ́ lẹ́yìn tí Éhúdù kú, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà.+ 2 Torí náà, Jèhófà fi wọ́n lé ọwọ́ Jábínì ọba Kénáánì,+ tó jọba ní Hásórì. Sísérà ni olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ó sì ń gbé ní Háróṣétì+ ti àwọn orílẹ̀-èdè.*
6 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà,+ torí náà Jèhófà fi wọ́n lé Mídíánì lọ́wọ́ fún ọdún méje.+