10 “Gbogbo ilẹ̀ náà láti Gébà+ dé Rímónì+ ní gúúsù Jerúsálẹ́mù yóò dà bí Árábà;+ yóò dìde, yóò sì máa gbé àyè rẹ̀,+ láti Ẹnubodè Bẹ́ńjámínì+ títí lọ dé ibi Ẹnubodè Àkọ́kọ́, títí lọ dé Ẹnubodè Igun àti láti Ilé Gogoro Hánánélì+ títí lọ dé àwọn ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì tó jẹ́ ti ọba.