27Nígbà tó di àárọ̀, gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa Jésù.+2 Lẹ́yìn tí wọ́n dè é, wọ́n mú un lọ, wọ́n sì fà á lé Pílátù lọ́wọ́, òun ni gómìnà.+
10 Síbẹ̀, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin ń dìde ṣáá, wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn án kíkankíkan. 11 Hẹ́rọ́dù àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ wá kàn án lábùkù,+ ó wọ aṣọ tó rẹwà fún un láti fi ṣe ẹlẹ́yà,+ ó sì ní kí wọ́n mú un pa dà sọ́dọ̀ Pílátù.