2 Sámúẹ́lì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́, Dáfídì dá Rékábù àti Báánà arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ Rímónì ará Béérótì lóhùn pé: “Bí Jèhófà ẹni tí ó yọ mí* nínú gbogbo wàhálà+ ti wà láàyè, Sáàmù 34:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìṣòro* olódodo máa ń pọ̀,+Àmọ́ Jèhófà ń gbà á sílẹ̀ nínú gbogbo rẹ̀.+ Sáàmù 37:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìgbàlà àwọn olódodo ti wá;+Òun ni odi ààbò wọn ní àkókò wàhálà.+
9 Àmọ́, Dáfídì dá Rékábù àti Báánà arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ Rímónì ará Béérótì lóhùn pé: “Bí Jèhófà ẹni tí ó yọ mí* nínú gbogbo wàhálà+ ti wà láàyè,