Sáàmù 42:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọlọ́run mi, ìrẹ̀wẹ̀sì ti bá ẹ̀mí* mi.+ Ìdí nìyẹn tí mo fi rántí rẹ,+Láti ilẹ̀ Jọ́dánì àti àwọn téńté orí Hámónì,Láti Òkè Mísárì.*
6 Ọlọ́run mi, ìrẹ̀wẹ̀sì ti bá ẹ̀mí* mi.+ Ìdí nìyẹn tí mo fi rántí rẹ,+Láti ilẹ̀ Jọ́dánì àti àwọn téńté orí Hámónì,Láti Òkè Mísárì.*