Sáàmù 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?+ Kí nìdí tí o fi jìnnà sí mi láti gbà mí sílẹ̀,Tí o sì jìnnà sí igbe ìrora mi?+ Jòhánù 12:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí.
22 Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?+ Kí nìdí tí o fi jìnnà sí mi láti gbà mí sílẹ̀,Tí o sì jìnnà sí igbe ìrora mi?+
27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí.