-
Sáàmù 80:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, mú wa bọ̀ sípò;
Jẹ́ kí ojú rẹ tàn sí wa lára, kí a lè rí ìgbàlà.+