Sáàmù 25:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ta ni ẹni tó ń bẹ̀rù Jèhófà?+ Òun yóò kọ́ ẹni náà ní ọ̀nà tó yẹ kí ó yàn.+ נ [Núnì] 13 Yóò* gbádùn ohun rere,+Àwọn àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ yóò sì jogún ayé.+ Sáàmù 37:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+ 26 Ó máa ń yáni ní nǹkan látọkàn wá,+Ìbùkún sì ń dúró de àwọn ọmọ rẹ̀.
12 Ta ni ẹni tó ń bẹ̀rù Jèhófà?+ Òun yóò kọ́ ẹni náà ní ọ̀nà tó yẹ kí ó yàn.+ נ [Núnì] 13 Yóò* gbádùn ohun rere,+Àwọn àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ yóò sì jogún ayé.+
25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+ 26 Ó máa ń yáni ní nǹkan látọkàn wá,+Ìbùkún sì ń dúró de àwọn ọmọ rẹ̀.