Jẹ́nẹ́sísì 13:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ábúrámù wá sọ fún Lọ́ọ̀tì+ pé: “Jọ̀ọ́, kò yẹ kí ìjà wáyé láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín àwọn tó ń da ẹran mi àti àwọn tó ń da ẹran rẹ, torí arákùnrin ni wá. Jòhánù 13:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Èyí ni gbogbo èèyàn máa fi mọ̀ pé ọmọ ẹ̀yìn mi ni yín, tí ìfẹ́ bá wà láàárín yín.”+ Kólósè 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́, yàtọ̀ sí gbogbo àwọn nǹkan yìí, ẹ fi ìfẹ́ wọ ara yín láṣọ,+ nítorí ó jẹ́ ìdè ìrẹ́pọ̀ pípé.+ Hébérù 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ túbọ̀ máa ní ìfẹ́ ará.+
8 Ábúrámù wá sọ fún Lọ́ọ̀tì+ pé: “Jọ̀ọ́, kò yẹ kí ìjà wáyé láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín àwọn tó ń da ẹran mi àti àwọn tó ń da ẹran rẹ, torí arákùnrin ni wá.
14 Àmọ́, yàtọ̀ sí gbogbo àwọn nǹkan yìí, ẹ fi ìfẹ́ wọ ara yín láṣọ,+ nítorí ó jẹ́ ìdè ìrẹ́pọ̀ pípé.+