Máàkù 1:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ní àárọ̀ kùtù, tí ilẹ̀ ò tíì mọ́, ó dìde, ó jáde lọ síbi tó dá, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà níbẹ̀.+