Jẹ́nẹ́sísì 34:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Dínà ọmọbìnrin tí Líà+ bí fún Jékọ́bù sábà máa ń lọ sọ́dọ̀* àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ náà.+ 2 Nígbà tí Ṣékémù, ọmọ Hámórì, ọmọ Hífì,+ tó jẹ́ ìjòyè ilẹ̀ náà rí i, ó mú un, ó sì bá a sùn, ó fipá bá a lò pọ̀.
34 Dínà ọmọbìnrin tí Líà+ bí fún Jékọ́bù sábà máa ń lọ sọ́dọ̀* àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ náà.+ 2 Nígbà tí Ṣékémù, ọmọ Hámórì, ọmọ Hífì,+ tó jẹ́ ìjòyè ilẹ̀ náà rí i, ó mú un, ó sì bá a sùn, ó fipá bá a lò pọ̀.