Òwe 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹni tí kò bá ka ìbáwí sí á di òtòṣì, á sì kan àbùkù,Àmọ́ ẹni tó bá ń gba ìtọ́sọ́nà* ni a ó gbé ga.+ Mátíù 7:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Torí náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tó sì ṣe é máa dà bí ọkùnrin kan tó ní òye, tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí àpáta.+ 25 Òjò sì rọ̀, omi kún àkúnya, ìjì sì fẹ́ lu ilé náà, àmọ́ kò wó, torí pé orí àpáta ni ìpìlẹ̀ rẹ̀ wà.
18 Ẹni tí kò bá ka ìbáwí sí á di òtòṣì, á sì kan àbùkù,Àmọ́ ẹni tó bá ń gba ìtọ́sọ́nà* ni a ó gbé ga.+
24 “Torí náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tó sì ṣe é máa dà bí ọkùnrin kan tó ní òye, tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí àpáta.+ 25 Òjò sì rọ̀, omi kún àkúnya, ìjì sì fẹ́ lu ilé náà, àmọ́ kò wó, torí pé orí àpáta ni ìpìlẹ̀ rẹ̀ wà.