Sáàmù 141:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn. Òwe 15:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni tó bá ń kọ ìbáwí kórìíra ẹ̀mí* rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó bá ń gba ìbáwí ní òye.*+ Hébérù 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Lóòótọ́, kò sí ìbáwí tó jẹ́ ohun ayọ̀ báyìí, àmọ́ ó máa ń dunni;* síbẹ̀, tó bá yá, ó máa ń so èso àlàáfíà ti òdodo fún àwọn tí a ti fi dá lẹ́kọ̀ọ́.
5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn.
11 Lóòótọ́, kò sí ìbáwí tó jẹ́ ohun ayọ̀ báyìí, àmọ́ ó máa ń dunni;* síbẹ̀, tó bá yá, ó máa ń so èso àlàáfíà ti òdodo fún àwọn tí a ti fi dá lẹ́kọ̀ọ́.