Sáàmù 37:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Máa fiyè sí aláìlẹ́bi,*Kí o sì máa wo adúróṣinṣin,+Nítorí àlàáfíà ń dúró de ẹni yẹn ní ọjọ́ ọ̀la.+ Òwe 16:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Láti yẹra fún ohun búburú ni ọ̀nà àwọn adúróṣinṣin. Ẹni tó bá ń ṣọ́ ọ̀nà rẹ̀ ń dáàbò bo ẹ̀mí* rẹ̀.+ 1 Pétérù 1:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní báyìí tí ẹ ti fi ìgbọràn yín sí òtítọ́ wẹ ara yín* mọ́, tí èyí sì mú kí ẹ ní ìfẹ́ ará láìsí ẹ̀tàn,+ kí ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ sí ara yín látọkàn wá.+
37 Máa fiyè sí aláìlẹ́bi,*Kí o sì máa wo adúróṣinṣin,+Nítorí àlàáfíà ń dúró de ẹni yẹn ní ọjọ́ ọ̀la.+
17 Láti yẹra fún ohun búburú ni ọ̀nà àwọn adúróṣinṣin. Ẹni tó bá ń ṣọ́ ọ̀nà rẹ̀ ń dáàbò bo ẹ̀mí* rẹ̀.+
22 Ní báyìí tí ẹ ti fi ìgbọràn yín sí òtítọ́ wẹ ara yín* mọ́, tí èyí sì mú kí ẹ ní ìfẹ́ ará láìsí ẹ̀tàn,+ kí ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ sí ara yín látọkàn wá.+