1 Àwọn Ọba 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí náà, ọrọ̀+ àti ọgbọ́n+ Ọba Sólómọ́nì pọ̀ ju ti gbogbo àwọn ọba yòókù láyé. Òwe 15:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọ̀pọ̀ ìṣúra ló wà nínú ilé olódodo,Àmọ́ èso* ẹni burúkú máa ń fa wàhálà bá a.+