Sáàmù 37:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Má banú jẹ́* nítorí àwọn ẹni burúkúTàbí kí o jowú àwọn aṣebi.+ Òwe 23:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí ọkàn rẹ má ṣe jowú àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àmọ́ kí o máa bẹ̀rù Jèhófà láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+