Sáàmù 120:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo gbé, nítorí mo jẹ́ àjèjì ní Méṣékì!+ Mò ń gbé láàárín àwọn àgọ́ Kídárì.+ Ìsíkíẹ́lì 27:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 O gba àwọn Árábù àti gbogbo ìjòyè Kídárì+ síṣẹ́, àwọn tó ń fi ọ̀dọ́ àgùntàn, àgbò àti ewúrẹ́ ṣòwò.+
21 O gba àwọn Árábù àti gbogbo ìjòyè Kídárì+ síṣẹ́, àwọn tó ń fi ọ̀dọ́ àgùntàn, àgbò àti ewúrẹ́ ṣòwò.+