Àìsáyà 54:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+ Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+
5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+ Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+