Diutarónómì 32:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀. Diutarónómì 33:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó sì di ọba ní Jéṣúrúnì,*+Nígbà tí àwọn olórí àwọn èèyàn náà kóra jọ,+Pẹ̀lú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì.+ Diutarónómì 33:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Kò sí ẹni tó dà bí Ọlọ́run tòótọ́+ Jéṣúrúnì,+Tó ń la ọ̀run kọjá kó lè ràn ọ́ lọ́wọ́,Tó sì ń gun àwọsánmà* nínú ọlá ńlá rẹ̀.+
15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.
26 Kò sí ẹni tó dà bí Ọlọ́run tòótọ́+ Jéṣúrúnì,+Tó ń la ọ̀run kọjá kó lè ràn ọ́ lọ́wọ́,Tó sì ń gun àwọsánmà* nínú ọlá ńlá rẹ̀.+