2 Àwọn Ọba 15:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Lákòókò yẹn, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í rán Résínì ọba Síríà àti Pékà+ ọmọ Remaláyà láti gbógun ti Júdà.+ 2 Kíróníkà 28:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Pékà+ ọmọ Remaláyà pa ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) ní Júdà ní ọjọ́ kan, gbogbo wọn jẹ́ akíkanjú ọkùnrin, èyí sì ṣẹlẹ̀ nítorí pé wọ́n ti fi Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀.+
6 Pékà+ ọmọ Remaláyà pa ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) ní Júdà ní ọjọ́ kan, gbogbo wọn jẹ́ akíkanjú ọkùnrin, èyí sì ṣẹlẹ̀ nítorí pé wọ́n ti fi Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀.+