Àìsáyà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Láyé ìgbà Áhásì+ ọmọ Jótámù ọmọ Ùsáyà, ọba Júdà, Résínì ọba Síríà àti Pékà+ ọmọ Remaláyà, ọba Ísírẹ́lì wá gbógun ja Jerúsálẹ́mù, àmọ́ kò* ṣẹ́gun rẹ̀.+
7 Láyé ìgbà Áhásì+ ọmọ Jótámù ọmọ Ùsáyà, ọba Júdà, Résínì ọba Síríà àti Pékà+ ọmọ Remaláyà, ọba Ísírẹ́lì wá gbógun ja Jerúsálẹ́mù, àmọ́ kò* ṣẹ́gun rẹ̀.+