Róòmù 9:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Yàtọ̀ síyẹn, Àìsáyà kéde nípa Ísírẹ́lì pé: “Bí iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tiẹ̀ pọ̀ bí iyanrìn òkun, àṣẹ́kù wọn nìkan ni a ó gbà là.+ 28 Nítorí Jèhófà* máa ní kí gbogbo ayé jíhìn, á parí rẹ̀, kò sì ní fi falẹ̀.”*+
27 Yàtọ̀ síyẹn, Àìsáyà kéde nípa Ísírẹ́lì pé: “Bí iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tiẹ̀ pọ̀ bí iyanrìn òkun, àṣẹ́kù wọn nìkan ni a ó gbà là.+ 28 Nítorí Jèhófà* máa ní kí gbogbo ayé jíhìn, á parí rẹ̀, kò sì ní fi falẹ̀.”*+