2 Àwọn Ọba 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọdún kẹta Hóṣéà+ ọmọ Élà ọba Ísírẹ́lì, Hẹsikáyà+ ọmọ Áhásì+ ọba Júdà di ọba. 2 Àwọn Ọba 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó tún ṣẹ́gun àwọn Filísínì+ títí dé Gásà àti àwọn ìpínlẹ̀ rẹ̀, láti ilé ìṣọ́ títí dé ìlú olódi.*