Sáàmù 103:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kì í fìgbà gbogbo wá àṣìṣe,+Kì í sì í bínú títí lọ.+ Àìsáyà 21:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀yin èèyàn mi tí wọ́n ti pa bí ọkà,Ohun tó tinú ibi ìpakà mi jáde,*+Mo ti sọ ohun tí mo gbọ́ fún ọ látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Míkà 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+
10 Ẹ̀yin èèyàn mi tí wọ́n ti pa bí ọkà,Ohun tó tinú ibi ìpakà mi jáde,*+Mo ti sọ ohun tí mo gbọ́ fún ọ látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì.
18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+