Sáàmù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Má ṣe jẹ́ kí ìṣísẹ̀ mi kúrò ní ọ̀nà rẹKí n má bàa kọsẹ̀.+ Sáàmù 37:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+ Òwe 16:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Fi gbogbo ohun tí o bá ń ṣe lé Jèhófà lọ́wọ́,*+Ohun tí o fẹ́ ṣe á sì yọrí sí rere. Òwe 20:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jèhófà ló ń darí ìṣísẹ̀ èèyàn;+Báwo ni èèyàn ṣe lè lóye ọ̀nà ara rẹ̀?*