Àìsáyà 30:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wọ́n lọ sí Íjíbítì+ láì fọ̀rọ̀ lọ̀ mí,*+Láti wá ààbò lọ sọ́dọ̀ Fáráò,*Kí wọ́n sì fi òjìji Íjíbítì ṣe ibi ìsádi wọn! Àìsáyà 31:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà. Ìdárò 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 A ti tẹ́ ọwọ́ wa sí Íjíbítì+ àti Ásíríà,+ ká lè rí oúnjẹ tí ó tó jẹ. Ìsíkíẹ́lì 16:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 O bá àwọn ọmọ Íjíbítì ṣèṣekúṣe,+ àwọn aládùúgbò rẹ oníṣekúṣe,* iṣẹ́ aṣẹ́wó rẹ tó bùáyà sì múnú bí mi. Ìsíkíẹ́lì 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ níkẹyìn, ọba náà ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ sí Íjíbítì, kí wọ́n lè fún un ní àwọn ẹṣin+ àti ọmọ ogun púpọ̀.+ Ṣé ó máa ṣàṣeyọrí? Ǹjẹ́ ẹni tó ń ṣe nǹkan wọ̀nyí á bọ́ lọ́wọ́ ìyà? Ṣé ó lè da májẹ̀mú kó sì mú un jẹ?’+
2 Wọ́n lọ sí Íjíbítì+ láì fọ̀rọ̀ lọ̀ mí,*+Láti wá ààbò lọ sọ́dọ̀ Fáráò,*Kí wọ́n sì fi òjìji Íjíbítì ṣe ibi ìsádi wọn!
31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà.
26 O bá àwọn ọmọ Íjíbítì ṣèṣekúṣe,+ àwọn aládùúgbò rẹ oníṣekúṣe,* iṣẹ́ aṣẹ́wó rẹ tó bùáyà sì múnú bí mi.
15 Àmọ́ níkẹyìn, ọba náà ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ sí Íjíbítì, kí wọ́n lè fún un ní àwọn ẹṣin+ àti ọmọ ogun púpọ̀.+ Ṣé ó máa ṣàṣeyọrí? Ǹjẹ́ ẹni tó ń ṣe nǹkan wọ̀nyí á bọ́ lọ́wọ́ ìyà? Ṣé ó lè da májẹ̀mú kó sì mú un jẹ?’+