-
Jeremáyà 51:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ẹ má ṣègbé nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.
Nítorí àkókò ẹ̀san Jèhófà ti tó.
Ó máa san ohun tó ṣe pa dà fún un.+
-
-
Jeremáyà 51:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Màá san án pa dà fun Bábílónì àti fún gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kálídíà
Nítorí gbogbo búburú tí wọ́n ti ṣe ní Síónì lójú yín,”+ ni Jèhófà wí.
-