-
Jeremáyà 32:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 “‘Àwọn èèyàn á fi owó ra ilẹ̀, wọ́n á ṣe ìwé àdéhùn tí wọ́n fi rà á, wọ́n á gbé èdìdì lé e, wọ́n á sì pe àwọn ẹlẹ́rìí ní ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì,+ ní agbègbè Jerúsálẹ́mù àti ní àwọn ìlú Júdà,+ ní àwọn ìlú tó wà ní àwọn agbègbè olókè àti ní àwọn ìlú tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀+ pẹ̀lú àwọn ìlú tó wà ní gúúsù, torí pé màá mú àwọn èèyàn wọn tó wà lóko ẹrú pa dà wá,’+ ni Jèhófà wí.”
-