-
Àìsáyà 56:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Màá tẹ́wọ́ gba odindi ẹbọ sísun wọn àtàwọn ẹbọ wọn lórí pẹpẹ mi.
Torí a ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà fún gbogbo èèyàn.”+
-
-
Míkà 4:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,
A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,
Àwọn èèyàn á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+
-