Jeremáyà 30:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí, “wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá kó àwọn èèyàn mi, Ísírẹ́lì àti Júdà, tó wà lóko ẹrú jọ,”+ ni Jèhófà wí, “màá mú wọn pa dà wá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá wọn, yóò sì pa dà jẹ́ tiwọn.”’”+
3 Nítorí, “wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá kó àwọn èèyàn mi, Ísírẹ́lì àti Júdà, tó wà lóko ẹrú jọ,”+ ni Jèhófà wí, “màá mú wọn pa dà wá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá wọn, yóò sì pa dà jẹ́ tiwọn.”’”+