Àìsáyà 60:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+ Àìsáyà 61:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní tiyín, a ó máa pè yín ní àlùfáà Jèhófà;+Wọ́n á máa pè yín ní òjíṣẹ́ Ọlọ́run wa. Ẹ máa jẹ ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+Ẹ sì máa fi ògo* wọn yangàn.
5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+
6 Ní tiyín, a ó máa pè yín ní àlùfáà Jèhófà;+Wọ́n á máa pè yín ní òjíṣẹ́ Ọlọ́run wa. Ẹ máa jẹ ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+Ẹ sì máa fi ògo* wọn yangàn.