Àìsáyà 22:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ pé: “Ẹ yí ojú yín kúrò lọ́dọ̀ mi,Màá sì sunkún gidigidi.+ Ẹ má fi dandan sọ pé ẹ fẹ́ tù mí nínúTorí ìparun ọmọbìnrin* àwọn èèyàn mi.+ Jeremáyà 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìrora mi pọ̀,* ìrora mi pọ̀! Ọkàn mi* gbọgbẹ́. Àyà mi ń lù kìkì. Mi ò lè dákẹ́,Nítorí mo* ti gbọ́ ìró ìwo Àti ìró ogun.*+ Ìsíkíẹ́lì 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bí wọ́n ṣe ń pa wọ́n, ó wá ku èmi nìkan, mo bá dojú bolẹ̀, mo sì ké jáde pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Ṣé inú tó ń bí ọ sí Jerúsálẹ́mù máa mú kí o pa gbogbo àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lì run ni?”+
4 Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ pé: “Ẹ yí ojú yín kúrò lọ́dọ̀ mi,Màá sì sunkún gidigidi.+ Ẹ má fi dandan sọ pé ẹ fẹ́ tù mí nínúTorí ìparun ọmọbìnrin* àwọn èèyàn mi.+
19 Ìrora mi pọ̀,* ìrora mi pọ̀! Ọkàn mi* gbọgbẹ́. Àyà mi ń lù kìkì. Mi ò lè dákẹ́,Nítorí mo* ti gbọ́ ìró ìwo Àti ìró ogun.*+
8 Bí wọ́n ṣe ń pa wọ́n, ó wá ku èmi nìkan, mo bá dojú bolẹ̀, mo sì ké jáde pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Ṣé inú tó ń bí ọ sí Jerúsálẹ́mù máa mú kí o pa gbogbo àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lì run ni?”+