Sáàmù 90:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+ Dáníẹ́lì 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Mò ń wò títí a fi gbé àwọn ìtẹ́ kalẹ̀, tí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ sì jókòó.+ Aṣọ rẹ̀ funfun bíi yìnyín,+ irun orí rẹ̀ sì dà bí ẹ̀gbọ̀n òwú. Ọwọ́ iná ni ìtẹ́ rẹ̀; iná tó ń jó ni àgbá kẹ̀kẹ́ rẹ̀.+ Dáníẹ́lì 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 títí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ fi dé, tí a sì dá àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ láre,+ àkókò tí a yàn pé kí àwọn ẹni mímọ́ gba ìjọba sì dé.+ Hábákúkù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà, ṣebí láti ayérayé ni ìwọ ti wà?+ Ọlọ́run mi, Ẹni Mímọ́ mi, ìwọ kì í kú.*+ Jèhófà, ìwọ lo yàn wọ́n láti ṣèdájọ́;Àpáta mi,+ o lò wọ́n láti fìyà jẹni.*+
2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+
9 “Mò ń wò títí a fi gbé àwọn ìtẹ́ kalẹ̀, tí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ sì jókòó.+ Aṣọ rẹ̀ funfun bíi yìnyín,+ irun orí rẹ̀ sì dà bí ẹ̀gbọ̀n òwú. Ọwọ́ iná ni ìtẹ́ rẹ̀; iná tó ń jó ni àgbá kẹ̀kẹ́ rẹ̀.+
22 títí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ fi dé, tí a sì dá àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ láre,+ àkókò tí a yàn pé kí àwọn ẹni mímọ́ gba ìjọba sì dé.+
12 Jèhófà, ṣebí láti ayérayé ni ìwọ ti wà?+ Ọlọ́run mi, Ẹni Mímọ́ mi, ìwọ kì í kú.*+ Jèhófà, ìwọ lo yàn wọ́n láti ṣèdájọ́;Àpáta mi,+ o lò wọ́n láti fìyà jẹni.*+